Ẹ́sítà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí wọn mú ayaba Fásítì wá ṣíwájúu rẹ̀, ti òun ti adé ọba rẹ̀, kí ó lè wá fi ẹwà rẹ̀ hàn àwọn ènìyàn àti àwọn ọlọ́lá, nítorí tí ó rẹwà.

Ẹ́sítà 1

Ẹ́sítà 1:7-12