Ẹ́sítà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tó ṣẹlẹ̀ ní ìgbà Sérísésì, tí ó jọba lórí ẹ̀tàdínláàdóje ìletò bẹ̀rẹ̀ láti Índíà títí ó fi dé Etiópíà. (Kúsì)

Ẹ́sítà 1

Ẹ́sítà 1:1-4