Ẹ́sírà 8:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nínú àwọn ọmọ Ṣekaníáyà;nínú àwọn ọmọ Párósì, Ṣekaríáyà, àti pé àádọ́jọ (150) ọkùnrin fi orùkọ sílẹ̀ pẹ̀lú rẹ;

Ẹ́sírà 8

Ẹ́sírà 8:1-13