Ẹ́sírà 8:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti Ásábáyà, pẹ̀lú Jésáíyà láti ìran Mérárì, pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ àti àwọn ọmọ wọ́n jẹ́ ogún (20) ọkùnrin.

Ẹ́sírà 8

Ẹ́sírà 8:18-25