Ẹ́sírà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni àwọ̀n olórí ìdílé àti àwọn tí ó fi orúkọ sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn tì wọn gòkè pẹ̀lú mi làti Bábílónì ní àkókò ìjọba Aritaṣéṣéṣì ọba:

Ẹ́sírà 8

Ẹ́sírà 8:1-10