Ẹ́sírà 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo pàṣẹ pé ẹnikẹ́ni nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà àti àwọn Léfì, ti ó wà ní abẹ́ ìṣàkòóso ìjọba mi, tí ó bá fẹ́ láti bá ọ lọ sí Jérúsálẹ́mù lè tẹ̀lé ọ lọ.

Ẹ́sírà 7

Ẹ́sírà 7:11-14