Ẹ́sírà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síwájú sí i, mo pàṣẹ pé tí ẹnikẹ́ni bá yí àṣẹ yìí padà, kí fa igi àjà ilé rẹ̀ yọ jáde, kí a sì gbe dúró, kí a si fi òun náà kọ́ sí orí rẹ̀ kí ó wo ilé rẹ̀ palẹ̀ a ó sì sọ ọ́ di ààtàn.

Ẹ́sírà 6

Ẹ́sírà 6:2-15