Ẹ́sírà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ní àkókò ìjọba Aritaṣéṣéṣì ọba Páṣíà, Bíṣílámì, Mítírédátì, Tábélì àti àwọn ẹlẹ́gbẹ̀ rẹ̀ yóòkù kọ̀wé sí Aritaṣéṣéṣì. A kọ ìwé náà ní ìlànà ìkọ̀wé Árámáíkì èdè Árámáíkì sì ní a fi kọ ọ́.

Ẹ́sírà 4

Ẹ́sírà 4:1-10