Ẹ́sírà 4:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí, iṣẹ́ lórí ilé Ọlọ́run ní Jérúsálẹ́mù wá sí ìdúró jẹ́ẹ́ títí di ọdún kejì ìjọba Dáríúsì ọba Páṣíà.

Ẹ́sírà 4

Ẹ́sírà 4:23-24