Ẹ́sírà 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíwájú síi, ọba gbọdọ̀ mọ̀ pé tí a bá kọ́ ìlú yìí àti tí a sì tún àwọn ògiri rẹ̀ mọ, kò sí owó orí, owó òde tàbí owó ibodè tí a ó san, owó tí ó sì ń wọlé fún ọba yóò sì dínkù.

Ẹ́sírà 4

Ẹ́sírà 4:3-18