Ẹ́sírà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú ìyìn àti ọpẹ́ ni wọ́n kọrin sí Olúwa:“Ó dára;ìfẹ́ rẹ̀ sí Ísírẹ́lì dúró títí láé.”Gbogbo àwọn ènìyàn sì fi ohùn ariwo ńlá yin Olúwa, nítorí tí a ti fi ìpìlẹ̀ ilé Olúwa lélẹ̀.

Ẹ́sírà 3

Ẹ́sírà 3:6-12