Ẹ́sírà 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkèdè kan jáde lọ jákèjádò Júdà àti Jérúsálẹ́mù fún gbogbo àwọn ìgbèkùn láti péjọ sí Jérúsálẹ́mù.

Ẹ́sírà 10

Ẹ́sírà 10:3-17