Ẹ́sírà 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tókù:Nínú ìran Párósì:Rámíáyà, Ísíáyà, Málíkíjà, Míjámínì, Éléásánì, Málíkíjà àti Bénáíyà.

Ẹ́sírà 10

Ẹ́sírà 10:24-35