Ẹ́sírà 10:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì ọmọ Ásáhélì àti Jáhéséáyà ọmọ Jíkífà nìkan pẹ̀lú àtìlẹyìn Mésísúlámù àti Ṣíábétaì ará Léfì, ni wọ́n tako àbá yìí.

Ẹ́sírà 10

Ẹ́sírà 10:11-18