Àwọn tí ó ń jẹ ohun dáradáradi òtòsì ní òpópó.Àwọn tí a fi aṣọ dáradára wọ̀ni wọ́n sùn ní orí òkítì eérú.