Ẹkún Jeremáyà 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ṣẹlẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wòlíìàti àìṣedédé àwọn olórí àlùfáà,tí ó ta ẹ̀jẹ̀ àwọn olódodosílẹ̀ láàrin rẹ̀.

Ẹkún Jeremáyà 4

Ẹkún Jeremáyà 4:10-19