Ẹkún Jeremáyà 3:53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n gbìyànjú láti mú òpin dé bá ayé mi nínú ihòwọ́n sì ju òkúta lù mí.

Ẹkún Jeremáyà 3

Ẹkún Jeremáyà 3:47-59