Ẹkún Jeremáyà 3:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dídára ni Olúwa fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀,sí àwọn tí ó ń wá a.

Ẹkún Jeremáyà 3

Ẹkún Jeremáyà 3:23-28