Ẹkún Jeremáyà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa dà bí ọ̀tá;ó gbé Ísírẹ́lì mì.Ó ti gbé gbogbo ààfin rẹ̀ mìó pa ibi gíga rẹ̀ run.Ó sọ ìmí ẹ̀dùn àti ìbànújẹ́ di púpọ̀fún àwọn ọmọbìnrin Júdà.

Ẹkún Jeremáyà 2

Ẹkún Jeremáyà 2:1-14