Ẹkún Jeremáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìbínú gbígbóná rẹ̀ ni ó kégbogbo ìwo Ísírẹ́lì.Ó ti mú ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ kúrònígbà tí àwọn ọ̀tá dé.Ó run ní Jákọ́bù bí ọ̀wọ́ inání àgọ́ àwọn ọmọbìnrin Síónì.

Ẹkún Jeremáyà 2

Ẹkún Jeremáyà 2:1-5