Ẹkún Jeremáyà 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìran àwọn wòlíì rẹjẹ́ kìkì ẹ̀tàn láìní ìwọ̀n;wọn kò sì fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ hàntí yóò mú ìgbèkùn kúrò fún ọ.Àwọn òrìṣà tí wọ́n fún ọjẹ́ èké àti ìsìnà.

Ẹkún Jeremáyà 2

Ẹkún Jeremáyà 2:9-16