Ẹkún Jeremáyà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú mi kọ̀ láti sunkún,mo ń jẹ ìrora nínú mi,mo tú ọkàn mi jáde sí ilẹ̀nítorí a pa àwọn ènìyàn mí run,nítorí àwọn ọmọdé àti ọmọ ọwọ́ ń kúní òpópó ìlú.

Ẹkún Jeremáyà 2

Ẹkún Jeremáyà 2:7-13