“Olúwa, wòó, bí mo ti wà nínú ìnira!Tí mo sì ń jẹ̀rora nínú mi,ìdààmú dé bá ọkàn minítorí pé a ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi gidigidi.Ní gbangba ni idà ń parun;ikú wà nínú ilé pẹ̀lú.