Ẹkún Jeremáyà 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ̀ṣẹ̀ mi ti di síṣopọ̀ sí àjàgà;ọwọ́ ọ rẹ̀ ni a fi hun ún papọ̀.Wọ́n ti yí ọrùn mi ká Olúwa sì ti dín agbára mi kù.Ó sì ti fi mí léàwọn tí n kò le dojúkọ lọ́wọ́.

Ẹkún Jeremáyà 1

Ẹkún Jeremáyà 1:12-22