Ẹkún Jeremáyà 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò ha jẹ́ nǹkankan sí i yín?Gbogbo ẹ̀yin tí ń ré kọjá,Ǹjẹ́ ẹnìkan ń jìyà bí èmi ti ń jìyàtí a fi fún mi, ti Olúwa mú wá fún miní ọjọ́ ìbínú gbígbóná rẹ̀.

Ẹkún Jeremáyà 1

Ẹkún Jeremáyà 1:9-22