Ékísódù 7:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹja tí ó wà nínú odò Náìlì yóò kú, odò náà yóò sì máa rùn, àwọn ará Éjíbítì kò sì ni lè mu omi rẹ̀.’ ”

Ékísódù 7

Ékísódù 7:8-19