Ékísódù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí sì tún fi idi májẹ̀mu mi múlẹ̀ pẹ̀lú wọn láti fún wọn ní ilẹ̀ Kénánì, ilẹ̀ tí wọn gbé gẹ́gẹ́ bí àjòjì.

Ékísódù 6

Ékísódù 6:3-8