Ékísódù 6:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élíásárì ọmọ Árónì fẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọbìnrin Pútíẹ́lì ní ìyàwó, ó sì bí Fínéhásì fún un.Ìwọ̀nyí ni olórí àwọn Léfì ni ìdílé ìdílé.

Ékísódù 6

Ékísódù 6:17-30