Ékísódù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì fẹ́ Élíṣahẹ́ba ọmọbìnrin Ámínádábù tí í ṣe arábìnrin Náhísíhónì, ó sì bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítamárì.

Ékísódù 6

Ékísódù 6:18-30