Ékísódù 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn:Gésónì, Kóhábì àti Mérárì: Léfì lo ẹ̀tàndínlógóje (137) ọdún láyé.

Ékísódù 6

Ékísódù 6:7-19