Ékísódù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ, sọ fún Fáráò ọba Éjíbítì pé kí ó jẹ́ kí àwọn ará Ísírẹ́lì lọ kúró ní orílẹ̀ èdè rẹ̀.”

Ékísódù 6

Ékísódù 6:4-18