Ékísódù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ̀yin kò ní láti pèsè koríko gbígbẹ fún bíríkì síṣun mọ́ fún àwọn ènìyàn wọ̀nyí; ẹ jẹ́ kí wọn máa wá koríko gbígbẹ fún ara wọn.

Ékísódù 5

Ékísódù 5:3-12