Ékísódù 5:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn sì wí pé, “Kí Olúwa kí ó wò yín, kí ó sì ṣe ìdájọ́! Ẹ̀yin ti mú wa dàbí òórùn búburú fún Fáráò àti àwọn òsìṣẹ̀ rẹ̀, ẹ sì ti fún wọn ni ìdà láti fi pa wá.”

Ékísódù 5

Ékísódù 5:14-23