Ékísódù 40:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè kò sì lè wọ inú Àgọ́ àjọ, nítorí àwọ́ọ́sánmọ̀ wà lórí rẹ, ògo Olúwa sì ti kún inú Àgọ́ náà.

Ékísódù 40

Ékísódù 40:27-36