Ékísódù 40:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì gbé àgbàlá tí ó yí Àgọ́ náà kà ró àti pẹpẹ, ó sì ta aṣọ títa ti ẹnu ọ̀nà sí àgbàlá náà. Bẹ́ẹ̀ Mósè ṣe parí iṣẹ náà

Ékísódù 40

Ékísódù 40:27-38