Ékísódù 40:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbé pẹpẹ ẹbọ sísun sí ẹ̀gbẹ́ ẹnu ọ̀nà Àgọ́, àgọ́ àjọ, ó sì rú ẹbọ sísun àti ẹbọ oúnjẹ́ (ọkà), gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún-un.

Ékísódù 40

Ékísódù 40:27-31