Ékísódù 40:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbé ọ̀pá fìtílà sínú àgọ́ àjọ ní òkánkán tábìlì ní ìhà gúsù Àgọ́ náà.

Ékísódù 40

Ékísódù 40:17-27