Ékísódù 40:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta òróró sí wọn ní orí gẹ́gẹ́ bí o ti ta òróró sí baba wọn ńi orí, nítorí kì wọn lè máa sìn mi bí àlùfáà. Ìtasórí wọn yóò jẹ́ iṣẹ́ àlùfáà ti yóò máa lò fún gbogbo ìrandíran tó ń bọ̀.”

Ékísódù 40

Ékísódù 40:9-21