Ékísódù 4:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

mo sọ fún ọ, “Jẹ́ kí ọmọ mi lọ, ki òun kí ó lè máa sìn mí.” Ṣùgbọ́n ìwọ kọ̀ láti jẹ́ kí ó lọ; nítorí náà, èmi yóò pa àkọ́bí ọmọ rẹ ọkùnrin.’ ”

Ékísódù 4

Ékísódù 4:16-31