Ékísódù 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò bá ọ sọ̀rọ̀ sí àwọn ènìyàn, yóò sì dàbí i pé ẹnu un rẹ ni a gbà sọ ọ̀rọ̀ náà, ìwọ yóò sì dàbí Ọlọ́run ní iwájú rẹ̀.

Ékísódù 4

Ékísódù 4:12-17