Ékísódù 39:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

aṣọ títa ti àgbàlá pẹ̀lú àwọn òpó rẹ̀ àti àgbàlá, àti aṣọ títa fún ẹnu ọ̀nà àgbàlá; ọ̀já àmùrè àti èèkàn àgọ́ fún àgbàlá náà; gbogbo ohun ọ̀ṣọ́ fún àgọ́, àgọ́ àjọ náà;

Ékísódù 39

Ékísódù 39:37-42