Ékísódù 39:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe àwo, adé mímọ́, láti ara kìkì wúrà, wọ́n sì kọ̀wé sí i, gẹ́gẹ́ bí i ìkọ̀wé lórí èdìdì: “MÍMỌ́ SÍ Olúwa.”

Ékísódù 39

Ékísódù 39:26-39