Ékísódù 39:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ, wọ́n ṣe àwọ̀tẹ́lẹ̀ ti ọ̀gbọ̀ dáradára tí iṣẹ́ alásọ híhun.

Ékísódù 39

Ékísódù 39:18-32