Ékísódù 39:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n jẹ́ òkúta méjìlá ọkan fún orúkọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ̀ọ̀kan, a fín ọ̀kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí èdìdì pẹ̀lú orúkọ ẹnikọ̀ọ̀kan ẹ̀yà méjèèjìlá.

Ékísódù 39

Ékísódù 39:11-24