Ékísódù 39:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú aṣọ aláró, ti elésèé àlùkò àti ti òdòdó ni wọ́n fi ṣe aṣọ híhun fún àwọn òsìsẹ́ ní ibi mímọ́. Ó sì tún dá aṣọ mímọ́ fún Árónì gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè.

Ékísódù 39

Ékísódù 39:1-5