Ékísódù 38:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìwọ̀n gíráàmù márùn-ún ààbọ̀ (5. 5 grams) lórí ẹnìkọ̀ọ̀kan, gẹ́gẹ́ bí sékélì ibi mímọ́, lórí olúkúlùkù ẹni tí ó ti kọjá tí a ti kà, láti ẹni ogún ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, àròpọ̀ wọ́n jẹ́ ọgbọ̀n-ọ̀kẹ́-lé-ẹgbẹ̀tadínlógún-ó-lé-àádọ́jọ ọkùnrin (603,550 men).

Ékísódù 38

Ékísódù 38:25-30