Ékísódù 38:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

pẹ̀lú òpó mẹ́rin àti ihò ìtẹ̀bọ̀ idẹ mẹ́rin. Ìkọ́ àti ìgbànú wọn jẹ́ fàdákà, a sì bo orí wọn pẹ̀lú fàdákà.

Ékísódù 38

Ékísódù 38:15-26