Ékísódù 37:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó se ìbòrí àánú kìkì wúrà ìgbọ̀nwọ́ méjì àti ààbọ̀ gígùn rẹ̀ àti ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀ ni fífẹ̀ rẹ̀.

Ékísódù 37

Ékísódù 37:1-10