Ékísódù 37:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kìkì wúrà ni ó fi bo orí rẹ̀, gbogbo ìhà rẹ̀ àti ìwo rẹ̀, ó sì fi ìgbátí wúrà yìí ká.

Ékísódù 37

Ékísódù 37:24-29