Ékísódù 37:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì se ọ̀pá fìtílà náà àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ láti ara talẹ́ńtì kan tí ó jẹ́ kìkì wúrà.

Ékísódù 37

Ékísódù 37:20-28